OLUFEMI
Si o ololufe mi
Moti ba opolopo pade
Sugbon Iwo tayo
Nitori o mu idunnun wa funmi
Awon kan ti wa, won tan mi.
Sugbon ooto no gbogbo iwo
O so wipe, o femi. Osi se be
Ife re wa ninu sise.
Oje ki okan re wa fun emi nikan
Mo ni alafia ninu ifere
Ade ni o je simi
Ohun iyebiye to okan mi fe nigbogbo igba
N o fe so e nu laya laye
Ose ti o femi

(Yoruba version of ' To Mai Love')
OMÓJUWÚRÀ

1 Like

03 Oct, 20
Story By: Omojuwura
No comment on this post
You have to be Logged in to add a comment