Ni akoko kan n’ilu Oloke-meje, Eni-ibukun, alufa orisa Atinuke ranse ikilo si afin oba pe, fun ojo meje, enikan ko gbodo rinde ale, ope ju ago meje, kolu kuluku ti wa n’ile re. kabiyesi ......
Enikan ni n bi mo, igba eniyan ni n wo. Eniyan kan ole da omo bi bi eniyan kan ose le da je eniyan. Die nibi, die lohun, ni gbogbo re fi n di odidi. Iya Akebaje o mon be rara, oro pe apa ohun nikan le ......
Kole baje Odami lo ju, ko le baje. Ohun ti Oluwa base Ko le baje. Alasepe ni olorun Kin se ise re labo Kin sore ede Kin se ore etan Adiitu ni ise re Ko fasiri re sowo eda kan Bo ba ti se, oti ......
Edakun eso fumi, semo jebi? E bami gboro na wo. Eese ti Adewale sehun bu mi, to hun so fun mi pe, imu mi di, mi o gborun. Kilode, kilosele? O ni, ohun ni ifemi pupo. O hun ti ko aye ohun yi mi ka. Bi mo ......
Ige-Adunbi ti rin rin rin, ohun wa ohun ti o sonu kaakiri. Ibo ni ko ti de? Oti de gusu, oti de ariwa, o mon ila orun, iwo orun loti wa. Ofe bo ninu isoro to wa. Bo tin lo kaakiri na lon wa ona abayo, ......
Lotoni opolopo ohun iyebiye ni owa nile Adulawo. Opolopo eniyan to ni iwon to kunju. Awon obinrin bi egbun, Won ni ewa ninu de ita. Awon okunrin bi oba, Okun won n gbe ile duro. Ani won lopo. Beni ......